Diutaronomi 18:20 BM

20 Ṣugbọn wolii tí ó bá fi orúkọ mi jẹ́ iṣẹ́ tí n kò rán an, tabi tí ó jẹ́ iṣẹ́ kan fun yín ní orúkọ àwọn oriṣa, wolii náà gbọdọ̀ kú ni.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 18

Wo Diutaronomi 18:20 ni o tọ