Diutaronomi 18:8 BM

8 Bákan náà ni wọn yóo jọ pín oúnjẹ wọn láìka ohun tí àwọn ará ilé rẹ̀ bá fi ranṣẹ sí i gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó kàn án ninu ogún baba rẹ̀ tí wọ́n tà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 18

Wo Diutaronomi 18:8 ni o tọ