Diutaronomi 19:14 BM

14 “Ninu ogún tìrẹ tí ó bá kàn ọ́ ninu ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín láti gbà, o kò gbọdọ̀ sún ohun tí àwọn baba ńlá rẹ bá fi pààlà ilẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 19

Wo Diutaronomi 19:14 ni o tọ