17 kí àwọn mejeeji tí wọn ń ṣe àríyànjiyàn yìí wá siwaju OLUWA, níwájú àwọn alufaa ati àwọn tí wọ́n jẹ́ onídàájọ́ nígbà náà.
Ka pipe ipin Diutaronomi 19
Wo Diutaronomi 19:17 ni o tọ