Diutaronomi 19:20 BM

20 Àwọn yòókù yóo gbọ́, ẹ̀rù yóo bà wọ́n, wọn kò sì ní ṣe irú nǹkan burúkú bẹ́ẹ̀ mọ́ láàrin yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 19

Wo Diutaronomi 19:20 ni o tọ