Diutaronomi 2:25 BM

25 Láti òní lọ, n óo mú kí ẹ̀rù yín máa ba gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà láyé yìí, tí wọ́n bá gbúròó yín, wọn yóo máa gbọ̀n, ojora yóo sì mú wọn nítorí yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 2

Wo Diutaronomi 2:25 ni o tọ