Diutaronomi 2:33 BM

33 OLUWA Ọlọrun wa fi lé wa lọ́wọ́, a ṣẹgun rẹ̀, ati òun ati àwọn ọmọ rẹ̀, ati gbogbo àwọn eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 2

Wo Diutaronomi 2:33 ni o tọ