Diutaronomi 2:36 BM

36 Láti Aroeri tí ó wà ní etí àfonífojì Anoni lọ, ati ìlú ńlá tí ó wà ní àfonífojì, títí dé Gileadi, kò sí ìlú tí ó ju agbára wa lọ. OLUWA Ọlọrun wa fi gbogbo wọn lé wa lọ́wọ́,

Ka pipe ipin Diutaronomi 2

Wo Diutaronomi 2:36 ni o tọ