4 Nítorí OLUWA Ọlọrun yín ń ba yín lọ láti bá àwọn ọ̀tá yín jà, ati láti fun yín ní ìṣẹ́gun.’
Ka pipe ipin Diutaronomi 20
Wo Diutaronomi 20:4 ni o tọ