Diutaronomi 23:5 BM

5 Ṣugbọn OLUWA Ọlọrun yín kò fetí sí ti Balaamu, ó yí èpè náà sí ìre fun yín nítorí pé ó fẹ́ràn yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 23

Wo Diutaronomi 23:5 ni o tọ