Diutaronomi 23:9 BM

9 “Nígbà tí ẹ bá jáde lọ láti bá àwọn ọ̀tá yín jagun, tí ẹ bá sì wà ninu àgọ́, ẹ níláti yẹra fún ohunkohun tíí ṣe ibi.

Ka pipe ipin Diutaronomi 23

Wo Diutaronomi 23:9 ni o tọ