Diutaronomi 24:21 BM

21 Bí ẹ bá ti ká èso àjàrà yín, ẹ kò gbọdọ̀ pada sẹ́yìn láti ká àwọn èso tí ẹ bá gbàgbé. Ẹ fi wọ́n sílẹ̀ fún àwọn àlejò ati àwọn opó ati àwọn aláìní baba.

Ka pipe ipin Diutaronomi 24

Wo Diutaronomi 24:21 ni o tọ