Diutaronomi 24:3 BM

3 ṣugbọn tí kò tún wu ọkọ titun náà, tí òun náà tún já ìwé ìkọ̀sílẹ̀ fún un, tí ó sì tún tì í jáde kúrò ninu ilé rẹ̀, tabi tí ọkọ keji tí obinrin yìí fẹ́ bá kú,

Ka pipe ipin Diutaronomi 24

Wo Diutaronomi 24:3 ni o tọ