Diutaronomi 25:6 BM

6 Wọn yóo ka ọmọkunrin kinni tí opó yìí bá bí sí ọmọ ọkọ rẹ̀ tí ó kú, kí orúkọ ọkọ rẹ̀ náà má baà parẹ́ ní Israẹli.

Ka pipe ipin Diutaronomi 25

Wo Diutaronomi 25:6 ni o tọ