Diutaronomi 26:11 BM

11 kí o sì bẹ̀rẹ̀ sí yọ̀ fún ohun tí OLUWA fún ìwọ ati ìdílé rẹ, kí àwọn ọmọ Lefi ati àwọn àlejò tí ń gbé ààrin yín náà sì máa bá ọ ṣe àjọyọ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 26

Wo Diutaronomi 26:11 ni o tọ