Diutaronomi 26:3 BM

3 Tọ alufaa tí ó wà lẹ́nu iṣẹ́ ní àkókò náà lọ, kí o sì wí fún un pé, ‘Mò ń wí fún OLUWA Ọlọrun mi lónìí pé, mo ti dé ilẹ̀ tí ó ti búra fún àwọn baba wa láti fún wa.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 26

Wo Diutaronomi 26:3 ni o tọ