Diutaronomi 28:14 BM

14 tí o kò bá yipada ninu àwọn òfin tí mo ṣe fún ọ lónìí, tí o kò sì sá tọ àwọn oriṣa lọ, láti máa bọ wọ́n.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:14 ni o tọ