Diutaronomi 28:48 BM

48 Nítorí náà, ní ìhòòhò, pẹlu ebi ati òùngbẹ, ati àìní ni ẹ óo fi máa sin àwọn ọ̀tá tí OLUWA yóo rán si yín, yóo sì la àjàgà irin bọ̀ yín lọ́rùn títí tí yóo fi pa yín run.

Ka pipe ipin Diutaronomi 28

Wo Diutaronomi 28:48 ni o tọ