Diutaronomi 29:13 BM

13 kí ó lè fi ìdí yín múlẹ̀ bí eniyan rẹ̀, kí ó sì máa jẹ́ Ọlọrun yín; gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí fun yín, ati bí ó ti búra fún Abrahamu, Isaaki, ati Jakọbu àwọn baba ńlá yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 29

Wo Diutaronomi 29:13 ni o tọ