Diutaronomi 29:2 BM

2 Mose pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ ti rí gbogbo ohun tí OLUWA ṣe sí Farao ati àwọn iranṣẹ rẹ̀, ati gbogbo ilẹ̀ rẹ̀, ní ilẹ̀ Ijipti.

Ka pipe ipin Diutaronomi 29

Wo Diutaronomi 29:2 ni o tọ