Diutaronomi 30:18 BM

18 mo wí fun yín gbangba lónìí pé, ẹ óo parun. Ẹ kò ní pẹ́ rárá lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń gòkè Jọdani lọ gbà, tí yóo sì di tiyín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 30

Wo Diutaronomi 30:18 ni o tọ