Diutaronomi 30:2 BM

2 tí ẹ bá yipada sí OLUWA Ọlọrun yín, ẹ̀yin ati àwọn ọmọ yín; tí ẹ bá tún ń gbọ́ tirẹ̀, tí ẹ sì ń fi tọkàntọkàn tẹ̀lé gbogbo òfin tí mo ṣe fun yín lónìí,

Ka pipe ipin Diutaronomi 30

Wo Diutaronomi 30:2 ni o tọ