Diutaronomi 31:9 BM

9 Mose bá kọ òfin yìí sílẹ̀, ó fún àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n ru àpótí majẹmu OLUWA ati gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli.

Ka pipe ipin Diutaronomi 31

Wo Diutaronomi 31:9 ni o tọ