Diutaronomi 32:22 BM

22 Nítorí iná ibinu mi ń jó,yóo sì jó títí dé isà òkú.Yóo jó ayé ati ohun gbogbo tí ń bẹ ninu rẹ̀ ní àjórun,tó fi mọ́ ìpìlẹ̀ àwọn òkè ńlá.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:22 ni o tọ