Diutaronomi 32:9 BM

9 Nítorí pé ìpín OLUWA ni àwọn eniyan rẹ̀,ó yan àwọn ọmọ Jakọbu ní ohun ìní fún ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:9 ni o tọ