Diutaronomi 33:26 BM

26 Ẹ̀yin ará Jeṣuruni,kò sí ẹni tí ó dàbí Ọlọrun yín,tí ó gun awọsanma lẹ́ṣin ninu ọlá ńlá rẹ̀,láti wá ràn yín lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:26 ni o tọ