Diutaronomi 33:5 BM

5 Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe di ọba ní Jeṣuruni,nígbà tí gbogbo àwọn olórí péjọ,àní, gbogbo àwọn olórí ninu ẹ̀yà Israẹli.

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:5 ni o tọ