Diutaronomi 34:8 BM

8 Àwọn ọmọ Israẹli ṣọ̀fọ̀ Mose fún ọgbọ̀n ọjọ́ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu, wọ́n sì parí ṣíṣe òkú rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 34

Wo Diutaronomi 34:8 ni o tọ