Diutaronomi 4:12 BM

12 Ọlọrun ba yín sọ̀rọ̀ láti inú iná náà wá, ẹ gbọ́ ohùn rẹ̀, ṣugbọn ẹ kò rí i. Ohùn rẹ̀ nìkan ni ẹ̀ ń gbọ́.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:12 ni o tọ