Diutaronomi 4:14 BM

14 OLUWA pàṣẹ fún mi nígbà náà, láti kọ yín ní ìlànà ati òfin rẹ̀, kí ẹ lè máa tẹ̀lé wọn ní ilẹ̀ tí ẹ̀ ń lọ gbà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:14 ni o tọ