Diutaronomi 4:20 BM

20 Ọlọrun ti yọ yín kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, ilẹ̀ tí ó dàbí iná ìléru ńlá, ó ko yín jáde láti jẹ́ eniyan rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti jẹ́ lónìí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:20 ni o tọ