Diutaronomi 8:16 BM

16 ẹni tí ó fi mana tí àwọn baba yín kò jẹ rí bọ́ yín ninu aṣálẹ̀, kí ó lè tẹ orí yín ba, kí ó sì dán yín wò láti ṣe yín ní rere níkẹyìn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 8

Wo Diutaronomi 8:16 ni o tọ