Diutaronomi 8:19 BM

19 Ṣugbọn, mò ń kìlọ̀ fun yín dáradára lónìí pé, bí ẹ bá gbàgbé OLUWA Ọlọrun yín, tí ẹ̀ ń sá káàkiri tọ àwọn oriṣa lẹ́yìn, tí ẹ sì ń bọ wọ́n, píparun ni ẹ óo parun.

Ka pipe ipin Diutaronomi 8

Wo Diutaronomi 8:19 ni o tọ