Diutaronomi 9:19 BM

19 Nítorí inú tí OLUWA ń bí si yín ati inú rẹ̀ tí kò dùn sí yín bà mí lẹ́rù, nítorí ó ti ṣetán láti pa yín run. Ṣugbọn OLUWA tún gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi nígbà náà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:19 ni o tọ