Diutaronomi 9:26 BM

26 Mo gbadura sí OLUWA, mo ní, ‘OLUWA Ọlọrun, má ṣe pa àwọn eniyan rẹ run. Ohun ìní rẹ ni wọ́n, àwọn tí o ti fi agbára rẹ rà pada, tí o fi ipá kó jáde láti ilẹ̀ Ijipti.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:26 ni o tọ