Diutaronomi 9:28 BM

28 kí àwọn ará ilẹ̀ tí o ti kó wa wá má baà wí pé, ‘OLUWA kò lè mú wọn lọ sí ilẹ̀ tí ó ṣèlérí fún wọn ati pé ó kórìíra wọn, ni ó ṣe kó wọn wá sinu aṣálẹ̀ láti pa wọ́n.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:28 ni o tọ