Lefitiku 11:41 BM

41 “Ohunkohun tí ń fi àyà fà lórí ilẹ̀ ayé jẹ́ ìríra, ẹnikẹ́ni kò sì gbọdọ̀ jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:41 ni o tọ