Lefitiku 14:18 BM

18 Alufaa yóo fi òróró tí ó kù ní ọwọ́ rẹ̀ ra orí ẹni tí wọ́n fẹ́ sọ di mímọ́. Lẹ́yìn náà, yóo ṣe ètùtù fún un níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:18 ni o tọ