Lefitiku 14:19 BM

19 “Alufaa yóo rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ láti ṣe ètùtù fún ẹni tí wọ́n fẹ́ sọ di mímọ́, lẹ́yìn náà, yóo pa ẹran ẹbọ sísun náà.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:19 ni o tọ