Lefitiku 14:34 BM

34 “Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ Kenaani tí n óo fun yín, tí yóo jẹ́ ohun ìní yín, bí mo bá fi àrùn ẹ̀tẹ̀ sí ilé kan ninu ilẹ̀ yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:34 ni o tọ