Lefitiku 19:17 BM

17 “Ẹ kò gbọdọ̀ di arakunrin yín sinu, ṣugbọn ẹ gbọdọ̀ máa sọ àsọyé pẹlu aládùúgbò yín, kí ẹ má baà gbẹ̀ṣẹ̀ nítorí tirẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:17 ni o tọ