Lefitiku 19:18 BM

18 Ẹ kò gbọdọ̀ gbẹ̀san, tabi kí ẹ di ọmọ eniyan yín sinu, ṣugbọn ẹ níláti fẹ́ràn ọmọnikeji yín gẹ́gẹ́ bí ara yín. Èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:18 ni o tọ