Lefitiku 19:31 BM

31 “Ẹ kò gbọdọ̀ kó ọ̀rọ̀ yín lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn aláyẹ̀wò tabi àwọn abókùúsọ̀rọ̀, kí wọ́n má baà sọ yín di aláìmọ́. Èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:31 ni o tọ