32 “Ẹ máa bu ọlá fún àwọn ogbó, kí ẹ máa bọ̀wọ̀ fún àwọn àgbà; kí ẹ sì máa bẹ̀rù Ọlọrun yín. Èmi ni OLUWA.
Ka pipe ipin Lefitiku 19
Wo Lefitiku 19:32 ni o tọ