Lefitiku 25:26 BM

26 Bí ẹni náà kò bá ní ẹbí tí ó lè ra ilẹ̀ náà pada, ṣugbọn ní ọjọ́ iwájú, tí nǹkan bá ń lọ déédé fún un, tí ó sì ní agbára láti ra ilẹ̀ náà pada,

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:26 ni o tọ