Lefitiku 25:40 BM

40 Jẹ́ kí ó wà lọ́dọ̀ rẹ bí alágbàṣe tabi bí àlejò; kí ó máa ṣiṣẹ́ fún ọ títí di ọdún jubili.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:40 ni o tọ