Lefitiku 25:41 BM

41 Nígbà náà ni yóo kúrò lọ́dọ̀ rẹ, òun ati àwọn ọmọ rẹ̀, yóo pada sí ọ̀dọ̀ àwọn eniyan rẹ̀, ati sórí ilẹ̀ ìní àwọn baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:41 ni o tọ