Lefitiku 26:10 BM

10 Ẹ óo jẹ àwọn nǹkan oko tí ẹ kó sí inú abà fún ọjọ́ pípẹ́, ẹ óo sì máa ru ìyókù wọn dànù kí ẹ lè rí ààyè kó tuntun sí.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:10 ni o tọ