Lefitiku 26:9 BM

9 N óo fi ojurere wò yín, n óo mú kí ẹ máa bímọlémọ, kí ẹ sì pọ̀ sí i, n óo sì fi ìdí majẹmu mi múlẹ̀ pẹlu yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:9 ni o tọ