Lefitiku 26:8 BM

8 Marun-un ninu yín yóo lé ọgọrun-un ọ̀tá sẹ́yìn, ọgọrun-un ninu yín yóo sì lé ẹgbaarun (10,000) àwọn ọ̀tá yín sẹ́yìn, idà ni ẹ óo fi máa pa wọ́n.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:8 ni o tọ